Ẹkisodu 40:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta òróró sí ara pẹpẹ ẹbọ sísun pẹlu, ati sí ara gbogbo àwọn ohun èlò rẹ̀, kí o ya pẹpẹ náà sí mímọ́, pẹpẹ náà yóo sì di ohun mímọ́ jùlọ.

Ẹkisodu 40

Ẹkisodu 40:3-14