Ẹkisodu 4:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Aaroni sọ gbogbo ohun tí OLUWA sọ fún Mose fún wọn, ó sì ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu náà lójú gbogbo àwọn àgbààgbà náà.

Ẹkisodu 4

Ẹkisodu 4:23-31