Ẹkisodu 39:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n fi irú aṣọ kan náà ṣe àmùrè dáradára kan. Àṣepọ̀ ni wọ́n ṣe é mọ́ efodu yìí láti máa fi so ó gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Ẹkisodu 39

Ẹkisodu 39:1-8