Ẹkisodu 39:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose wo gbogbo iṣẹ́ náà, ó rí i pé wọ́n ṣe é gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pa á láṣẹ, Mose sì súre fún wọn.

Ẹkisodu 39

Ẹkisodu 39:39-43