Ẹkisodu 38:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Idẹ yìí ni ó lò láti ṣe ìtẹ́lẹ̀ àwọn ìlẹ̀kùn àgọ́ àjọ, ati pẹpẹ onídẹ, ati àwọn idẹ inú rẹ̀ ati gbogbo àwọn ohun èlò ibi pẹpẹ náà.

Ẹkisodu 38

Ẹkisodu 38:23-31