Ẹkisodu 38:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe ìwo kọ̀ọ̀kan sí igun mẹrẹẹrin pẹpẹ náà, àṣepọ̀ mọ́ pẹpẹ ni ó ṣe àwọn ìwo náà, ó sì yọ́ idẹ bò wọ́n.

Ẹkisodu 38

Ẹkisodu 38:1-7