Ẹkisodu 38:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Aṣọ funfun onílà tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ ni wọ́n fi ṣe gbogbo aṣọ títa tí ó wà ninu àgbàlá náà.

Ẹkisodu 38

Ẹkisodu 38:6-18