Ẹkisodu 37:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Kerubu náà na ìyẹ́ wọn bo ìtẹ́ àánú náà; wọ́n kọjú sí ara wọn, wọ́n ń wo ìtẹ́ àánú.

Ẹkisodu 37

Ẹkisodu 37:1-13