Ẹkisodu 37:2-4 BIBELI MIMỌ (BM)

2. Ó yọ́ wúrà bò ó ninu ati lóde, ó sì tún fi wúrà ṣe ìgbátí rẹ̀.

3. Ó da òrùka wúrà mẹrin, ó jó ọ̀kọ̀ọ̀kan mọ́ igun kọ̀ọ̀kan àpótí ẹ̀rí náà, òrùka meji lẹ́gbẹ̀ẹ́ kinni, meji lẹ́gbẹ̀ẹ́ keji.

4. Ó fi igi akasia ṣe ọ̀pá, ó sì yọ́ wúrà bò wọ́n.

Ẹkisodu 37