Ẹkisodu 35:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ, ó wí fún wọn pé, “Àwọn nǹkan tí OLUWA pa láṣẹ pé kí ẹ máa ṣe nìwọ̀nyí:

Ẹkisodu 35

Ẹkisodu 35:1-11