Ẹkisodu 34:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli súnmọ́ ọn, ó sì ṣe gbogbo ohun tí Ọlọrun bá a sọ lórí òkè Sinai lófin fún wọn.

Ẹkisodu 34

Ẹkisodu 34:24-35