Ẹkisodu 34:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Aaroni, ati àwọn ọmọ Israẹli rí Mose, wọ́n ṣe akiyesi pé ojú rẹ̀ ń kọ mànàmànà, ẹ̀rù sì ń bà wọ́n láti súnmọ́ ọn.

Ẹkisodu 34

Ẹkisodu 34:29-32