Ẹkisodu 33:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan gbọ́ ìròyìn burúkú náà, ọkàn wọn bàjẹ́, kò sì sí ẹni tí ó fi ohun ọ̀ṣọ́ sí ara rárá.

Ẹkisodu 33

Ẹkisodu 33:1-7