Ẹkisodu 33:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ògo mi bá ń kọjá lọ, n óo pa ọ́ mọ́ ninu ihò òkúta yìí, n óo sì fi ọwọ́ mi bò ọ́ lójú nígbà tí mo bá ń rékọjá.

Ẹkisodu 33

Ẹkisodu 33:19-23