Ẹkisodu 32:7 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fún Mose pé, “Tètè sọ̀kalẹ̀, nítorí pé àwọn eniyan rẹ tí o kó ti ilẹ̀ Ijipti wá ti ba ara wọn jẹ́.

Ẹkisodu 32

Ẹkisodu 32:1-9