Ẹkisodu 32:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn eniyan náà bá bọ́ yẹtí wúrà etí wọn jọ, wọ́n kó wọn tọ Aaroni lọ.

Ẹkisodu 32

Ẹkisodu 32:1-6