Ẹkisodu 32:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Lefi sì ṣe gẹ́gẹ́ bí Mose ti wí, àwọn tí wọ́n kú láàrin àwọn eniyan náà tó ẹgbẹẹdogun (3,000) ọkunrin.

Ẹkisodu 32

Ẹkisodu 32:26-31