Ẹkisodu 30:34 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fún Mose pé, “Mú àwọn ohun ìkunra olóòórùn dídùn wọnyi: sitakite, ati onika, ati galibanumi ati ojúlówó turari olóòórùn dídùn, gbogbo wọn gbọdọ̀ jẹ́ ìwọ̀n kan náà.

Ẹkisodu 30

Ẹkisodu 30:25-38