Ẹkisodu 30:24 BIBELI MIMỌ (BM)

ati ẹẹdẹgbẹta (500) ìwọ̀n ṣekeli kasia, ìwọ̀n ṣekeli ilé OLUWA ni kí wọ́n lò láti wọ̀n wọ́n. Lẹ́yìn náà, mú ìwọ̀n hini ojúlówó òróró olifi kan.

Ẹkisodu 30

Ẹkisodu 30:16-25