Ẹkisodu 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Ọlọrun rí i pé ó súnmọ́ ọn láti wo ohun ìyanu náà, Ọlọrun pè é láti inú igbó náà, ó ní, “Mose! Mose!”Mose dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

Ẹkisodu 3

Ẹkisodu 3:1-8