Ẹkisodu 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli OLUWA farahàn án ninu ahọ́n iná láàrin ìgbẹ́; bí ó ti wò ó, ó rí i pé iná ń jó nítòótọ́, ṣugbọn igbó náà kò jóná.

Ẹkisodu 3

Ẹkisodu 3:1-7