Ẹkisodu 29:9 BIBELI MIMỌ (BM)

dì wọ́n lámùrè, kí o sì dé wọn ní fìlà. Bẹ́ẹ̀ ni kí o ṣe ya Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ sí mímọ́, atọmọdọmọ wọn yóo sì máa ṣe alufaa mi.

Ẹkisodu 29

Ẹkisodu 29:4-10