Ẹkisodu 29:44 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo ya àgọ́ àjọ ati pẹpẹ náà sí mímọ́, ati Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ pẹlu, kí wọ́n lè máa sìn mí gẹ́gẹ́ bí alufaa.

Ẹkisodu 29

Ẹkisodu 29:36-46