Ẹkisodu 29:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ meje ni o níláti fi ṣe ètùtù fún pẹpẹ, kí o sì yà á sí mímọ́, nígbà náà ni pẹpẹ náà yóo di mímọ́, ohunkohun tí ó bá sì kan pẹpẹ náà yóo di mímọ́ pẹlu.

Ẹkisodu 29

Ẹkisodu 29:30-46