Ẹkisodu 29:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ yóo sì jẹ ẹran àgbò náà, ati burẹdi tí ó wà ninu agbọ̀n, ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ àjọ.

Ẹkisodu 29

Ẹkisodu 29:24-35