Ẹkisodu 29:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyíkéyìí ninu àwọn ọmọ rẹ̀ tí ó bá di alufaa dípò rẹ̀ yóo wọ àwọn aṣọ wọnyi fún ọjọ́ meje, nígbà tí ó bá wá sí ibi àgọ́ àjọ.

Ẹkisodu 29

Ẹkisodu 29:27-35