Ẹkisodu 28:29 BIBELI MIMỌ (BM)

“Orúkọ àwọn ọmọ Israẹli yóo máa wà lára Aaroni, lórí ìgbàyà ìdájọ́, ní oókan àyà rẹ̀, nígbà tí ó bá wọ ibi mímọ́ lọ, fún ìrántí nígbà gbogbo níwájú OLUWA.

Ẹkisodu 28

Ẹkisodu 28:21-31