Ẹkisodu 28:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, da òrùka wúrà meji mìíràn, kí o dè wọ́n mọ́ ìsàlẹ̀ àwọn èjìká efodu, níwájú ibi tí ó ti so pọ̀ mọ́ àmùrè rẹ̀.

Ẹkisodu 28

Ẹkisodu 28:26-33