Ẹkisodu 28:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ ẹ̀yà mẹfa sára òkúta ekinni ati orúkọ ẹ̀yà mẹfa yòókù sára ekeji, kí o to àwọn orúkọ náà bí wọ́n ṣe bí wọn tẹ̀lé ara wọn.

Ẹkisodu 28

Ẹkisodu 28:1-20