Ẹkisodu 27:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí o ti àwọn ọ̀pá náà bọ àwọn òrùka ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ, tí ọ̀pá yóo fi wà ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji pẹpẹ náà nígbà tí wọ́n bá fẹ́ gbé e.

Ẹkisodu 27

Ẹkisodu 27:3-12