Ẹkisodu 27:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Fadaka ni kí o fi bo gbogbo òpó inú àgọ́ náà, fadaka náà ni kí o sì fi ṣe gbogbo ìkọ́ àwọn òpó náà, àfi àwọn ìtẹ́lẹ̀ rẹ̀ ni kí o fi idẹ ṣe.

Ẹkisodu 27

Ẹkisodu 27:7-20