Ẹkisodu 26:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Aadọta ojóbó ni kí o ṣe sí àránpọ̀ aṣọ kinni, lẹ́yìn náà ṣe aadọta ojóbó sí àránpọ̀ aṣọ keji, kí àwọn ojóbó náà lè kọ ojú sí ara wọn.

Ẹkisodu 26

Ẹkisodu 26:2-13