Ẹkisodu 26:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbé e kọ́ sórí òpó igi akasia mẹrin, tí ó ní ìkọ́ wúrà. Wúrà ni kí o yọ́ bo gbogbo òpó náà, kí wọ́n sì wà lórí ìtẹ́lẹ̀ fadaka mẹrin.

Ẹkisodu 26

Ẹkisodu 26:22-37