Ẹkisodu 25:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Fi igi akasia ṣe ọ̀pá, kí o sì yọ́ wúrà bò wọ́n; àwọn ọ̀pá wọnyi ni wọn yóo máa fi gbé tabili náà.

Ẹkisodu 25

Ẹkisodu 25:27-29