Ẹkisodu 25:23 BIBELI MIMỌ (BM)

“Fi igi akasia kan tabili kan, kí ó gùn ní ìwọ̀n igbọnwọ meji, kí ó fẹ̀ ní ìwọ̀n igbọnwọ kan, kí ó sì ga ní ìwọ̀n igbọnwọ kan ààbọ̀.

Ẹkisodu 25

Ẹkisodu 25:16-27