Ẹkisodu 24:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú ìwé majẹmu náà, ó kà á sí etígbọ̀ọ́ gbogbo àwọn eniyan, wọ́n sì dáhùn pé, “Gbogbo ohun tí OLUWA wí ni a óo ṣe, a óo sì gbọ́ràn.”

Ẹkisodu 24

Ẹkisodu 24:1-13