Ẹkisodu 24:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì rán àwọn kan ninu àwọn ọdọmọkunrin Israẹli, pé kí wọ́n lọ fi mààlúù rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia sí OLUWA.

Ẹkisodu 24

Ẹkisodu 24:3-11