Ẹkisodu 24:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fún Mose pé, “Gun orí òkè tọ̀ mí wá, kí o dúró sibẹ, n óo sì kó wàláà tí wọ́n fi òkúta ṣe fún ọ, tí mo kọ àwọn òfin ati ìlànà sí, fún ìtọ́ni àwọn eniyan yìí.”

Ẹkisodu 24

Ẹkisodu 24:8-18