Ẹkisodu 23:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹyọ oyún kan kò ní bàjẹ́ lára àwọn obinrin yín, bẹ́ẹ̀ ni ẹyọ obinrin kan kò ní yàgàn ninu gbogbo ilẹ̀ yín. N óo jẹ́ kí ẹ gbó, kí ẹ sì tọ́.

Ẹkisodu 23

Ẹkisodu 23:16-33