Ẹkisodu 21:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí olówó rẹ̀ bá fẹ́ aya fún un, tí aya náà sì bímọ fún un, lọkunrin ati lobinrin, olówó rẹ̀ ni ó ni aya ati àwọn ọmọ patapata, òun nìkan ni òfin dá sílẹ̀.

Ẹkisodu 21

Ẹkisodu 21:1-8