Ẹkisodu 20:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn èmi a máa fi ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ hàn sí ẹgbẹẹgbẹrun àwọn tí wọ́n fẹ́ mi, tí wọ́n sì ń pa òfin mi mọ́.

Ẹkisodu 20

Ẹkisodu 20:3-16