Ẹkisodu 20:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ bá fi òkúta tẹ́ pẹpẹ fún mi, ẹ má lo òkúta tí wọ́n bá gbẹ́, nítorí pé bí ẹ bá fi ohun èlò yín ṣiṣẹ́ lára òkúta náà, ẹ ti sọ ọ́ di aláìmọ́.

Ẹkisodu 20

Ẹkisodu 20:20-26