Ẹkisodu 20:12-15 BIBELI MIMỌ (BM)

12. “Bọ̀wọ̀ fún baba ati ìyá rẹ, kí ẹ̀mí rẹ lè gùn lórí ilẹ̀ tí èmi OLUWA Ọlọrun rẹ fi fún ọ.

13. “O kò gbọdọ̀ paniyan.

14. “O kò gbọdọ̀ ṣe panṣaga.

15. “O kò gbọdọ̀ jalè.

Ẹkisodu 20