Ẹkisodu 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọbinrin Farao dá a lóhùn pé, “Lọ pè é wá.” Ọmọbinrin náà bá yára lọ pe ìyá ọmọ náà.

Ẹkisodu 2

Ẹkisodu 2:1-15