Ẹkisodu 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó ṣí i, ó rí ọmọ kan ninu rẹ̀, ọmọ náà ń sọkún. Àánú ṣe é, ó wí pé, “Ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Heberu nìyí.”

Ẹkisodu 2

Ẹkisodu 2:1-13