Ẹkisodu 19:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, bí ẹ bá gbọ́ tèmi, tí ẹ sì pa majẹmu mi mọ́ ẹ óo jẹ́ tèmi láàrin gbogbo eniyan, nítorí pé tèmi ni gbogbo ayé yìí patapata;

Ẹkisodu 19

Ẹkisodu 19:4-12