Ẹkisodu 19:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá dá OLUWA lóhùn pé, “OLUWA, àwọn eniyan wọnyi kò lè gun òkè Sinai wá, nítorí pé ìwọ náà ni o pàṣẹ pé kí á pààlà yí òkè náà po, kí á sì yà á sí mímọ́.”

Ẹkisodu 19

Ẹkisodu 19:21-25