Ẹkisodu 19:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sọ fún un pé, “Sọ̀kalẹ̀ lọ, kí o sì kìlọ̀ fún àwọn eniyan náà, kí wọ́n má baà rọ́ wọ ibi tí OLUWA wà láti wò ó, kí ọpọlọpọ wọn má baà parun.

Ẹkisodu 19

Ẹkisodu 19:20-23