Ẹkisodu 18:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹtiro sì bá wọn yọ̀ nítorí gbogbo oore tí OLUWA ti ṣe fún àwọn ọmọ Israẹli, nítorí gbígbà tí ó gbà wọ́n kalẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti.

Ẹkisodu 18

Ẹkisodu 18:5-12