Ẹkisodu 18:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose dáhùn pé, “Ọ̀dọ̀ mi ni àwọn eniyan náà ti máa ń bèèrè ohun tí Ọlọrun fẹ́ kí wọ́n ṣe.

Ẹkisodu 18

Ẹkisodu 18:9-22